Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 12:46 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nínú ilé ni ẹ ti gbọdọ̀ jẹ ẹ́; ẹ kò gbọdọ̀ mú èyíkéyìí nínú ẹran náà jáde kúrò nínú ilé. Ẹ má ṣe ṣẹ́ ọ̀kankan nínú egungun rẹ̀.

Ka pipe ipin Ékísódù 12

Wo Ékísódù 12:46 ni o tọ