Olúwa sọ fún Mósè àti Árónì pé, “Ìwọ̀n yìí ni àwọn òfin fún àjọ ìrékọjá:“Àjòjì kò gbọdọ̀ jẹ nínú rẹ̀.