Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 12:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fáráò sì ránṣẹ́ pe Mósè àti Árónì ní òru, ó sì wí pé, “Ẹ kúrò lọ́dọ̀ mi ẹ̀yin àti àwọn ènìyàn Ísírẹ́lì! Ẹ lọ láti sin Olúwa gẹ́gẹ́ bí ẹ ti béèrè.

Ka pipe ipin Ékísódù 12

Wo Ékísódù 12:31 ni o tọ