Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 12:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ sọ fún wọn ni ìgbà náà, ‘Ẹbọ ìrékọjá sí Olúwa ni, ẹni tí ó rékọjá ilé e wa ni ìgbà tí ó kọlu àwọn ara Éjíbítì. Tí ó si da wa sí nígbà ti ó pa àwọn ara Éjíbítì.’ ” Àwọn ènìyàn sì tẹríba láti sìn.

Ka pipe ipin Ékísódù 12

Wo Ékísódù 12:27 ni o tọ