Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 12:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fún ọjọ́ méje ni ẹ̀yin yóò fi jẹ àkàrà tí kò ní ìwúkàrà. Ní ọjọ́ kìn-ín-ní, ẹ ó gbé ìwúkàrà kúrò ni ilé yín, nítorí ẹnikẹ́ni tí ó bá jẹ ohunkóhun tí ó ni ìwúkàrà nínú láti ọjọ́ kìn-ín-ní di ọjọ́ keje ni kí a yọ kúrò ni Ísírẹ́lì.

Ka pipe ipin Ékísódù 12

Wo Ékísódù 12:15 ni o tọ