Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 11:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo àwọn ìjòyè rẹ̀ wọ̀nyí yóò tọ̀ mí wá, wọn yóò wólẹ̀ ni iwájú, mi wọn yóò sì máa wí pé, ‘Lọ àti àwọn ènìyàn tí ó tẹ̀ lé ọ!’ Lẹ́yìn náà èmi yóò jáde.” Nígbà náà ni Mósè fi ìbínú jáde kúrò ní iwájú Fáráò

Ka pipe ipin Ékísódù 11

Wo Ékísódù 11:8 ni o tọ