Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 11:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo àkọ́bí ọmọkùnrin tí ó wà ní ilẹ̀ Éjíbítì ni yóò kú, bẹ̀rẹ̀ lórí àkọ́bí ọkùnrin Fáráò tí ó jòkòó lórí ìtẹ́ rẹ̀, tí ó fi dé orí àkọ́bí ọmọkùnrin ti ẹrú-bìnrin tí ń lọ ọlọ àti gbogbo àkọ́bí ẹran ọ̀sìn pẹ̀lú.

Ka pipe ipin Ékísódù 11

Wo Ékísódù 11:5 ni o tọ