Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 11:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè àti Árónì ṣe àwọn iṣẹ́ ìyanu wọ̀nyí níwájú Fáráò, ṣùgbọ́n Olúwa sé ọkàn Fáráò le, òun kò sí jẹ́ kí àwọn Ísírẹ́lì jáde kúrò ni orílẹ̀ èdè rẹ̀.

Ka pipe ipin Ékísódù 11

Wo Ékísódù 11:10 ni o tọ