Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 11:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nísínsìn yìí, Olúwa sọ fún Mósè pé èmi yóò mú ìyọnu kan sí i wá sí orí Fáráò àti ilẹ̀ Éjíbítì. Lẹ́yìn náà yóò jẹ́ kí ẹ̀yín kí ó lọ kúrò níhín yìí, nígbà tí ó bá sì ṣe bẹ́ẹ̀ yóò lé yín jáde pátápátá.

Ka pipe ipin Ékísódù 11

Wo Ékísódù 11:1 ni o tọ