Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 10:28-29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

28. Fáráò sọ fún Mósè pé, “Kúrò ní iwájú mi! Rí i dájú pé o kò wá sí iwájú mi mọ́! Ọjọ́ tí ìwọ bá rí ojú mi ni ìwọ yóò kú.”

29. Mósè sì dáhùn pé, gẹ́gẹ́ bí ìwọ ti wí, “Èmi kí yóò wá sí iwájú rẹ mọ́.”

Ka pipe ipin Ékísódù 10