Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 10:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fáráò sọ fún Mósè pé, “Kúrò ní iwájú mi! Rí i dájú pé o kò wá sí iwájú mi mọ́! Ọjọ́ tí ìwọ bá rí ojú mi ni ìwọ yóò kú.”

Ka pipe ipin Ékísódù 10

Wo Ékísódù 10:28 ni o tọ