Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 1:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn agbẹ̀bí náà sì dá Fáráò lóhùn pé, “Àwọn obìnrin Hébérù kò rí bí àwọn obìnrin Éjíbítì, wọ́n ní agbára, wọ́n sì ti máa ń bí ọmọ kí àwọn agbẹ̀bí tó dé ọ̀dọ̀ wọn.”

Ka pipe ipin Ékísódù 1

Wo Ékísódù 1:19 ni o tọ