Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ékísódù 1:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nígbà ti ẹ̀yin bá ń gbẹ̀bí àwọn obìnrin Hébérù, tí ẹ sì kíyèsí wọn lórí ìkúnlẹ̀ ìrọbí wọn, bí ó bá jẹ́ ọkùnrin ni ọmọ náà, ẹ pa á; ṣùgbọ́n bí ó bá jẹ́ obìnrin, ẹ jẹ́ kí ó wà láàyè.”

Ka pipe ipin Ékísódù 1

Wo Ékísódù 1:16 ni o tọ