Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 5:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ rìn ní gbogbo ọ̀nà tí Olúwa Ọlọ́run yín ti pàṣẹ fún un yín, kí ẹ bá à le yè, kí ó sì dára fún un yín, kí ọjọ́ ọ yín bá à lè pẹ́ ní ilẹ̀ tí ẹ̀yin yóò gbà.

Ka pipe ipin Deutarónómì 5

Wo Deutarónómì 5:33 ni o tọ