Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 5:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ìbá ti dára tó, bí ọkàn wọn bá lè bẹ̀rù mi, tí ó sì ń pa gbogbo òfin mi mọ́ nígbà gbogbo, kí ó bá à lè dára fún wọn, àti àwọn ọmọ wọn láéláé.

Ka pipe ipin Deutarónómì 5

Wo Deutarónómì 5:29 ni o tọ