Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 5:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Má ṣe ṣe ojúkòkòrò sí aya aládúgbò rẹ, má ṣe ṣe ojúkòkòrò sí ilé tàbí ilẹ̀ alábágbé rẹ, sí ẹrúkùnrin tàbí ẹrúbìnrin rẹ̀, màlúù tàbí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ rẹ̀, tàbí ohunkóhun tí í ṣe ti aládúgbò rẹ.”

Ka pipe ipin Deutarónómì 5

Wo Deutarónómì 5:21 ni o tọ