Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 5:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè sì pe gbogbo Ísírẹ́lì jọ, ó sì wí pé: Gbọ́ ìwọ Ísírẹ́lì, gbọ́ ìlànà àti òfin tí mo mú wá sí etíìgbọ ọ yín lónìí. Ẹ kọ wọ́n, kí ẹ sì ri dájú pé ẹ̀ ń ṣe wọ́n.

Ka pipe ipin Deutarónómì 5

Wo Deutarónómì 5:1 ni o tọ