Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 32:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n fi mí jowú nípa ohun tí kì í ṣe Ọlọ́run,wọ́n sì fi ohun aṣán an wọn mú mi bínú.Èmi yóò mú wọn kún fún ìlara láti ọ̀dọ̀ àwọn tí kì í ṣe ènìyàn;èmi yóò sì mú wọn bínú láti ọ̀dọ̀ aṣiwèrè orílẹ̀ èdè.

Ka pipe ipin Deutarónómì 32

Wo Deutarónómì 32:21 ni o tọ