Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 30:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ó ti lé ẹni rẹ kan sí ilẹ̀ tí ó jìnnà jù lábẹ́ ọ̀run, láti ibẹ̀ Olúwa Ọlọ́run rẹ yóò ṣà yín jọ yóò sì tún mú u yín padà.

Ka pipe ipin Deutarónómì 30

Wo Deutarónómì 30:4 ni o tọ