Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 30:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

kí ìwọ sì lè fẹ́ Olúwa Ọlọ́run rẹ, fetí sílẹ̀ sí ohùn un rẹ̀, kí o sì dúró ṣinṣin nínú rẹ̀. Nítorí Olúwa ni ìyè rẹ, yóò sì fún ọ ní ọdún púpọ̀ ní ilẹ̀ tí ó ti búra láti fi fún àwọn baba rẹ Ábúráhámù, Ísáákì àti Jákọ́bù.

Ka pipe ipin Deutarónómì 30

Wo Deutarónómì 30:20 ni o tọ