Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 30:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

èmi ń sọ fún un yín lónìí yìí pé ìwọ yóò parun láìsí àní-àní. O kò ní í gbé pẹ́ ní ilẹ̀ tí ìwọ ń kọjá Jọ́dánì láti gbà àti láti ní.

Ka pipe ipin Deutarónómì 30

Wo Deutarónómì 30:18 ni o tọ