Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 30:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́ẹ̀ ni kò sí ní ìhà kejì òkun, tí ìwọ ìbá fi wí pé, “Ta ni yóò rékọjá òkun lọ fún wa, tí yóò sì mú un wá fún wa, kí àwa lè gbọ́ ọ, kí a si le ṣe é?”

Ka pipe ipin Deutarónómì 30

Wo Deutarónómì 30:13 ni o tọ