Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 30:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí o bá gbọ́ ti Olúwa Ọlọ́run rẹ tí o sì pa òfin rẹ̀ mọ́ àti àṣẹ tí a kọ sínú ìwé òfin yìí kí o sì yípadà sí Olúwa Ọlọ́run rẹ pẹ̀lú gbogbo àyà rẹ àti pẹ̀lú gbogbo ọkàn rẹ.

Ka pipe ipin Deutarónómì 30

Wo Deutarónómì 30:10 ni o tọ