Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 28:49 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa yóò mú àwọn orílẹ̀ èdè wá sí ọ láti ọ̀nà jínjìn, bí òpin ayé, bí idì ti ń bẹ́ láti orí òkè sílẹ̀, orílẹ̀ èdè tí ìwọ kò gbọ́ èdè wọn.

Ka pipe ipin Deutarónómì 28

Wo Deutarónómì 28:49 ni o tọ