Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 28:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Màlúù rẹ yóò di pípa níwájú ù rẹ, ṣùgbọ́n ìwọ kì yóò jẹ ìkankan nínú rẹ̀. Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ rẹ yóò sì di mímú pẹ̀lú agbára kúrò lọ́dọ̀ rẹ, a kì yóò sì da padà. Àgùntàn rẹ yóò di mímú fún àwọn ọ̀ta rẹ, ẹnìkankan kò sì ní gbà á.

Ka pipe ipin Deutarónómì 28

Wo Deutarónómì 28:31 ni o tọ