Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 23:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí o bá wọ inú oko ọkà aládùúgbò rẹ, o lè fi ọwọ́ rẹ ya sírì rẹ̀, ṣùgbọ́n o kò gbọdọ̀ ki dòjé bọ ọkà tí ó dúró.

Ka pipe ipin Deutarónómì 23

Wo Deutarónómì 23:25 ni o tọ