Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 20:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí kò ṣe bẹ́ẹ̀, wọn yóò kọ́ ọ láti tẹ̀lé gbogbo ohun ìríra tí wọ́n ń ṣe nínú sísin àwọn ọlọ́run wọn, ìwọ yóò sì sẹ̀ sí Olúwa Ọlọ́run rẹ.

Ka pipe ipin Deutarónómì 20

Wo Deutarónómì 20:18 ni o tọ