Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 2:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fún àwọn ènìyàn náà ní àwọn òfin wọ̀nyí: ‘Ẹ ti fẹ́ la ilẹ̀ àwọn arákùnrin yín kọjá, àwọn ọmọ Ísọ̀; àwọn ará Édómù tí ń gbé ní Séírì. Ẹ̀rù yín yóò bà wọ́n, ṣùgbọ́n ẹ ṣọ́ra gidigidi.

Ka pipe ipin Deutarónómì 2

Wo Deutarónómì 2:4 ni o tọ