Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 12:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Níwájú Olúwa Ọlọ́run yín níbẹ̀, kí ẹ̀yin àti ìdílé yín jẹun kí ẹ sì yó, nínú gbogbo ìdáwọ́lé e yín, torí pé Olúwa Ọlọ́run yín ti bùkún un yín.

Ka pipe ipin Deutarónómì 12

Wo Deutarónómì 12:7 ni o tọ