Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Deutarónómì 11:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ẹ bá farabalẹ̀ kíyèsí àwọn òfin tí mo ń fún un yín, láti tẹ̀lé: Láti fẹ́ Olúwa Ọlọ́run yín, láti máa rìn ní gbogbo ọ̀nà rẹ̀ àti láti dìí mú ṣinṣin:

Ka pipe ipin Deutarónómì 11

Wo Deutarónómì 11:22 ni o tọ