Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 9:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò sì fi ìdí i májẹ̀mu kan múlẹ̀ pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ fún ọ̀sẹ̀ kan. Ní àárin ọ̀sẹ̀ ni yóò mú òpin bá ẹbọ àti ọrẹ ẹbọ. Àti lórí ìyẹ́ tẹ́ḿpìlì ni yóò dà ìríra sórí àwọn tí ó mú ìdahoro wá, títí tí òpin tí a ti pàṣẹ lórí asọnidahoro yóò fi padà fi dé bá a.”

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 9

Wo Dáníẹ́lì 9:27 ni o tọ