Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 9:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ̀yìn ọ̀ṣẹ̀ méjìlélọ́gọ́ta, a ó ké ẹni òróró náà kúrò, kò sì ní ní ohun kan. Àwọn ènìyàn alákòóso tí yóò wá ni yóò pa ìlú náà àti ibi mímọ́ run. Òpin yóò dé bí ìkún omi: ogun yóò máa jà títí dé òpin, a sì ti pàṣẹ ìdahoro.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 9

Wo Dáníẹ́lì 9:26 ni o tọ