Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 8:26-27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

26. “Ìran alẹ́ àti ti òwúrọ̀, tí a fi hàn ọ́ jẹ́ òtítọ́, ṣùgbọ́n pa ìran náà mọ́, nítorí pé, ó jẹ mọ́ ti ọjọ́ iwájú”

27. Èmi Dáníẹ́lì sì ṣe àárẹ̀ fún ọjọ́ mélòó kan. Nígbà náà, mo dìde, mo sì ń bá isẹ́ ọba lọ. Ìran náà sì bàmí lẹ́rù, kò sì yé mi.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 8