Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 8:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nípa àrékérekè rẹ̀, yóò mú kí ẹ̀tàn gbèrú, yóò gbé ara rẹ̀ ga nínú ọkàn rẹ̀, nígbà tí wọ́n rò wí pé àlàáfíà dé, yóò sì pa àwọn ènìyàn run, nígbà tí wọn kò rò tẹ́lẹ̀, yóò sì lòdì sí olórí àwọn ọmọ aládé, ṣíbẹ̀, a ó paárun ṣùgbọ́n kì í ṣe nípa agbára ènìyàn.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 8

Wo Dáníẹ́lì 8:25 ni o tọ