Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 8:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò di alágbára, ṣùgbọn tí kì í ṣe nípa agbára rẹ̀. Yóò sì máa ṣe ìparun tí yóò ya ni lẹ́nu, yóò sì máa ṣe àṣeyọri nínú ohun gbogbo tó ń ṣe. Yóò sì run àwọn alágbára àti àwọn ènìyàn mímọ́.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 8

Wo Dáníẹ́lì 8:24 ni o tọ