Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 8:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ó ṣe ń bá mi sọ̀rọ̀, mo ti sùn lọ fọnfọn, bí mo ṣe da ojú bolẹ̀. Nígbà náà ni ó fi ọwọ́ kàn mí, ó sì gbé mi dúró lórí ẹsẹ̀ mi.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 8

Wo Dáníẹ́lì 8:18 ni o tọ