Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 8:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ó ṣe súnmọ́ ibi tí mo dúró sí, ẹ̀rù bàmí, mo sì dọ̀bálẹ̀. Ó ń sọ fún mi pé, “Ọmọ ènìyàn, jẹ́ kí ó yé ọ pé ìran náà ń sọ nípa ìgbà ìkẹyìn ni.”

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 8

Wo Dáníẹ́lì 8:17 ni o tọ