Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 7:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò sọ̀rọ̀ odi sí ọ̀gá ògo, yóò sì pọ́n ẹni mímọ́ lójú, yóò sì gbèrò láti yí ìgbà àti òfin padà. A ó fi àwọn ẹni mímọ́ lé e lọ́wọ́ fún ìgbà díẹ̀, ní ọdún méjì àti ààbọ̀.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 7

Wo Dáníẹ́lì 7:25 ni o tọ