Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 7:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ó ṣe àlàyé yìí fún mi pé: ‘Ẹranko kẹrin ni ìjọba kẹrin tí yóò wà ní ayé. Yóò yàtọ̀ sí gbogbo àwọn ìjọba yóòkù yóò sì pa gbogbo ayé run, yóò tẹ̀ẹ́ mọ́lẹ̀, yóò sì fọ́ ọ́ sí wẹ́wẹ́.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 7

Wo Dáníẹ́lì 7:23 ni o tọ