Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 7:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo lọ bá ọ̀kan nínú àwọn tí ó dúró níbẹ̀, mo sì bi í léèrè òtítọ́ ìtúmọ̀ nǹkan wọ̀nyí.“Ó sọ fún mi, ó sì túmọ̀ àwọn nǹkan wọ̀nyí fún mi:

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 7

Wo Dáníẹ́lì 7:16 ni o tọ