Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 7:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọdún àkọ́kọ́ Beliṣáṣárì ọba Bábílónì, Dáníẹ́lì lá àlá kan, ìran náà sì wá sí ọkàn an rẹ̀ bí ó ṣe ṣùn sórí ibùṣùn un rẹ̀, ó sì kọ àlá náà sílẹ̀.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 7

Wo Dáníẹ́lì 7:1 ni o tọ