Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 4:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo wí pé, “Beliteṣásárì, olórí àwọn amòye, èmi mọ̀ wí pé ẹ̀mí Ọlọ́run mímọ́ wà nínú rẹ, kò sì sí àsírí kan tí ó ṣòro jù fún ọ. Sọ àlá mi kí o sì túmọ̀ rẹ̀ fún mi.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 4

Wo Dáníẹ́lì 4:9 ni o tọ