Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 3:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n tí kò bá rí bẹ́ẹ̀, a fẹ́ kí ìwọ ọba mọ̀ dájú wí pé àwa kò ní sin òrìṣà rẹ bẹ́ẹ̀ ni a kò ní fi orí balẹ̀ fún ère wúrà tí ìwọ gbé kalẹ̀.”

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 3

Wo Dáníẹ́lì 3:18 ni o tọ