Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 3:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ẹ̀yin bá jù wá sínú iná ìléru, Ọlọ́run tí àwa ń sìn lágbára láti gbà wá kúrò nínú un rẹ̀, yóò sì gbà wá lọ́wọ́ ọ̀ rẹ, ìwọ ọba.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 3

Wo Dáníẹ́lì 3:17 ni o tọ