Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 11:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ọba yóò ṣe bí ó ti wù ú yóò sì gbé ara rẹ̀ ga, ju gbogbo òrìṣà lọ, yóò máa sọ àwọn ọ̀rọ̀ tí kò-ṣe-é-gbọ́-létí sí Ọlọ́run àwọn Ọlọ́run, a yóò sì máa yege títí àkókò ìbínú yóò fi parí, nítorí ohun tí a ti pinnu yóò ṣẹlẹ̀.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 11

Wo Dáníẹ́lì 11:36 ni o tọ