Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 11:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pẹ̀lú ẹ̀tàn ni yóò bá àwọn tí ó ba májẹ̀mú jẹ́, ṣùgbọ́n, àwọn tí ó mọ Ọlọ́run wọn yóò jẹ́ alágbára. Wọn yóò sì kọjú ìjà sí i.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 11

Wo Dáníẹ́lì 11:32 ni o tọ