Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 11:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba àríwá yóò padà sí ilẹ̀ rẹ̀ pẹ̀lú ọrọ̀ púpọ̀, ṣùgbọ́n ọkàn rẹ̀ yóò lòdì sí májẹ̀mú mímọ́, yóò sì ṣiṣẹ́ lòdì sí i, yóò sì padà sí orílẹ̀-èdè oun fúnra rẹ̀.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 11

Wo Dáníẹ́lì 11:28 ni o tọ