Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 11:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Pẹ̀lú ogun púpọ̀, yóò sì ru agbára rẹ̀ àti ìgboyà rẹ̀ ṣókè sí ọba Gúṣù. Ọba Gúṣù yóò dìde ogun pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọmọ ogun tí ó lágbára gidigidi, ṣùgbọ́n kò ní leè dúró, nítorí ọ̀tẹ̀ tí ó gbérò sí i.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 11

Wo Dáníẹ́lì 11:25 ni o tọ