Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 11:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ní ìsinsìnyí, mo sọ òtítọ́ fún ọ ọba mẹ́ta yóò dìde sí i ní Páṣíà, àti ẹ̀kẹrin tí yóò jẹ́ ọlọ́rọ̀ ju gbogbo wọn lọ. Tí ó bá ti di alágbára nípa ọrọ̀ rẹ̀, yóò sì ru gbogbo wọn sókè lòdì sí ìjọba Gíríkì.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 11

Wo Dáníẹ́lì 11:2 ni o tọ