Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Dáníẹ́lì 1:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú un gbogbo ọ̀ràn, ọgbọ́n àti òyé tí ọba ń bèrè lọ́wọ́ ọ wọn, ó rí i pé wọ́n sàn ní ìlọ́po mẹ́wàá ju gbogbo àwọn amòye àti ọlọ́gbọn tí ó wà ní gbogbo ìjọba rẹ̀.

Ka pipe ipin Dáníẹ́lì 1

Wo Dáníẹ́lì 1:20 ni o tọ